
Kí ni ìkànnì yìí wà fún?
Ọ̀pọ̀ ọmọ Yorùbá ni ó hùn láti mọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkan nipa bóseńlọ àti ohun titun nínú sáyẹnsì àti ìmọ̀ ẹ̀rọ ṣugbọn wọn kò ní àǹfààní nítorí pé èdè gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n fi ń kọ àwọn ǹkan wọ̀nyìí.
Ìkànnì yìí wà fún múmú àwọn ìmọ̀ yìí wá fún wa lédè Yorùbá
